Main content

Kò sí ìdí tí à ó fi bínú sí Akeredolu, kò sí gómìnà tí kìí fẹ́ tẹ́ ààrẹ lọ́rùn nígbà mííràn- Ọ̀jọ̀gbọ́n Akintoye

Ọ̀jọ̀gbọ́n Bamji Akointoye ní kò ṣeéṣe fún àwọn olùpè fún Yorùbá Nation láti kó gbogbo ènìyàn ní túlásì pé kí wọ́n lọ fún Yorùbá Nation, bíkò 'se àwọn tó bá wù.

Release date:

Duration:

11 minutes

This clip is from

More clips from Iseju kan ѿý