Main content

Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Ko see ma gbo o jẹ iyipo awọn itan olokiki lojumọ lori oju opo wẹẹbu ѿý Yoruba
Ko see ma gbo o jẹ iyipo awọn itan olokiki lojumọ lori oju opo wẹẹbu ѿý Yoruba
www.bbcnews.com/Yoruba. O jẹ eto awọn iṣẹju-aaya 60 ti a ṣejade ni ọna kika ohun.
Ó ṣàkópọ̀ àkóónú ojoojúmọ́ tó ga jù lọ tí ѿý Yorùbá ń tẹ̀ jáde ní àwọn ẹ̀ka bí ìròyìn
tí ń lọ lọ́wọ́, àwọn tó ń ṣàlàyé nípa àwọn ọ̀rọ̀ tó ń lọ lọ́wọ́ àti iṣẹ́ akoroyin tó jẹ́
úóó.